ÌWÉ ÒWE 1:23

ÌWÉ ÒWE 1:23 YCE

Ẹ fetí sí ìbáwí mi, n óo ṣí ọkàn mi payá fun yín, n óo sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ mi ye yín.