Ọgbọ́n ń kígbe ní òpópónà, ó ń pariwo láàrin ọjà, ó ń kígbe lórí odi ìlú, ó ń sọ̀rọ̀ ní àwọn ẹnubodè ìlú, ó ní, “Ẹ̀yin aláìmọ̀kan, ẹ óo ti pẹ́ tó ninu àìmọ̀kan yín? Àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn yóo ti ní inú dídùn pẹ́ tó ninu ẹ̀gàn pípa wọn, tí àwọn òmùgọ̀ yóo sì kórìíra ìmọ̀? Ẹ fetí sí ìbáwí mi, n óo ṣí ọkàn mi payá fun yín, n óo sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ mi ye yín.
Kà ÌWÉ ÒWE 1
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ÌWÉ ÒWE 1:20-23
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò