Oòrùn ati òṣùpá ti ṣókùnkùn, àwọn ìràwọ̀ kò sì tan ìmọ́lẹ̀ mọ́. OLUWA kígbe láti Sioni, ó sọ̀rọ̀ láti Jerusalẹmu; ọ̀run ati ayé mì tìtì, ṣugbọn OLUWA ni ààbò fún àwọn eniyan rẹ̀, òun ni ibi ààbò fún Israẹli.
Kà JOẸLI 3
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: JOẸLI 3:15-16
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò