JOHANU 10:29-30

JOHANU 10:29-30 YCE

Ohun tí Baba mi ti fún mi tóbi ju ohun gbogbo lọ. Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó lè já a gbà mọ́ Baba mi lọ́wọ́. Ọ̀kan ni èmi ati Baba mi.”

Àwọn fídíò fún JOHANU 10:29-30