nítorí pé apanirun ti dé sí i, àní ó ti dé sí Babiloni. Ogun ti kó àwọn ọmọ ogun rẹ̀, àwọn ọ̀tá ti rún àwọn ọfà rẹ̀ jégéjégé, nítorí pé Ọlọrun ẹ̀san ni èmi OLUWA, dájúdájú n óo gbẹ̀san.
Kà JEREMAYA 51
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: JEREMAYA 51:56
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò