ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:25

ÌWÉ ONÍWÀÁSÙ 7:25 YCE

Mo tún pinnu láti kẹ́kọ̀ọ́, láti ṣe ìwádìí, ati láti wá ọgbọ́n, kí n mọ gbogbo nǹkan, ati ibi tí ń bẹ ninu ìwà òmùgọ̀, ati àìlóye tí ó wà ninu ìwà wèrè.