ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 9:22

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 9:22 YCE

Ṣugbọn ńṣe ni Saulu túbọ̀ ń lágbára sí i. Àwọn Juu tí ó ń gbé Damasku kò mọ ohun tí wọ́n le wí mọ́, nítorí ó fi ẹ̀rí hàn pé Jesu ni Mesaya.