ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:35

ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 27:35 YCE

Nígbà tí ó ti sọ báyìí tán, òun náà mú burẹdi, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun níwájú gbogbo wọn, ó bù ú, ó bá bẹ̀rẹ̀ sí jẹ ẹ́.