1
Sekariah 7:9
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Báyìí ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí pé: ‘Ṣe ìdájọ́ òtítọ́, kí ẹ sì ṣe àánú àti ìyọ́nú olúkúlùkù sí arákùnrin rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Sekariah 7:9
2
Sekariah 7:10
Má sì ṣe ni opó lára tàbí aláìní baba, àlejò, tàbí tálákà; kí ẹnikẹ́ni nínú yín má ṣe gbèrò ibi ní ọkàn sí arákùnrin rẹ̀.’
Ṣàwárí Sekariah 7:10
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò