1
Orin Solomoni 1:2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Fi ìfẹnukonu ìfẹ́ kò mí ní ẹnu, nítorí ìfẹ́ rẹ dára ju ọtí wáìnì lọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Orin Solomoni 1:2
2
Orin Solomoni 1:4
Fà mí lọ pẹ̀lú rẹ, kí a lọ kíákíá ọba ti mú mi wá sínú yàrá rẹ̀. Àwa yọ̀ inú wa sì dùn sí ọ; a gbé ìfẹ́ rẹ ga ju ọtí wáìnì lọ. Wọ́n fẹ́ ọ nítòótọ́!
Ṣàwárí Orin Solomoni 1:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò