1
Saamu 74:16
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Tìrẹ ni ọ̀sán, tìrẹ ni òru pẹ̀lú; ìwọ yà oòrùn àti òṣùpá.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 74:16
2
Saamu 74:12
Ṣùgbọ́n ìwọ Ọlọ́run ni ọba mi láti ìgbà pípẹ́; Ó mú ìgbàlà wá sórí ilẹ̀ ayé.
Ṣàwárí Saamu 74:12
3
Saamu 74:17
Ìwọ pààlà etí ayé; Ìwọ dá ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn àti ìgbà òtútù.
Ṣàwárí Saamu 74:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò