1
Saamu 57:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ṣàánú fún mi, Ọlọ́run, ṣàánú fún mi, nítorí nínú rẹ ni ààbò ọkàn mí wà. Èmi o fi ààbò mí sí ibi ìyẹ́ apá rẹ títí tí ewu yóò fi kọjá lọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 57:1
2
Saamu 57:10
Nítorí títóbi ní ìfẹ́ rẹ, tí ó dé ọ̀run; òtítọ́ rẹ tàn dé àwọsánmọ̀.
Ṣàwárí Saamu 57:10
3
Saamu 57:2
Mo kígbe sókè sí Ọlọ́run Ọ̀gá-ògo jùlọ, sí Ọlọ́run tó ń pa májẹ̀mú rẹ̀ mọ́ fún mi.
Ṣàwárí Saamu 57:2
4
Saamu 57:11
Gbígbéga ni ọ́, Ọlọ́run, ju àwọn ọ̀run lọ; kí ògo rẹ kí ó ju gbogbo ayé lọ.
Ṣàwárí Saamu 57:11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò