1
Saamu 55:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Gbé ẹrù rẹ lọ sí ọ̀dọ̀ OLúWA yóò sì mú ọ dúró; òun kò ní jẹ́ kí olódodo ṣubú.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 55:22
2
Saamu 55:17
Ní alẹ́, ní òwúrọ̀ àti ní ọ̀sán èmi sọkún jáde nínú ìpọ́njú, o sì gbọ́ ohùn mi.
Ṣàwárí Saamu 55:17
3
Saamu 55:23
Ṣùgbọ́n ìwọ, Ọlọ́run, ni yóò mu àwọn ọ̀tá mi wá sí ihò ìparun; Àwọn ẹni tí òǹgbẹ ẹ̀jẹ̀ ń gbẹ àti ẹni ẹ̀tàn, kì yóò gbé ààbọ̀ ọjọ́ wọn. Ṣùgbọ́n fún èmi, èmi gbẹ́kẹ̀lé ọ.
Ṣàwárí Saamu 55:23
4
Saamu 55:16
Ṣùgbọ́n èmi pe Ọlọ́run; OLúWA yóò sì gbà mí.
Ṣàwárí Saamu 55:16
5
Saamu 55:18
Ó rà mí padà láìléwu kúrò nínú ogun tí ó dìde sí mi, nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó dìde sí mi.
Ṣàwárí Saamu 55:18
6
Saamu 55:1
Fi etí sí àdúrà mi, Ọlọ́run, Má ṣe fi ojú pa ẹ̀bẹ̀ mi rẹ́
Ṣàwárí Saamu 55:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò