1
Saamu 31:24
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Jẹ́ alágbára, yóò sì mú yín ní àyà le gbogbo ẹ̀yin tí ó dúró de OLúWA.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 31:24
2
Saamu 31:15
Ìgbà mi ń bẹ ní ọwọ́ rẹ; gbà mí kúrò ní ọwọ́ àwọn ọ̀tá mi àti àwọn onínúnibíni.
Ṣàwárí Saamu 31:15
3
Saamu 31:19
Báwo ni títóbi oore rẹ̀ ti pọ̀ tó, èyí tí ìwọ ti ní ní ìpamọ́ fún àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ, èyí tí ìwọ rọ̀jò rẹ̀ níwájú àwọn ènìyàn tí wọ́n fi ọ́ ṣe ibi ìsádi wọn.
Ṣàwárí Saamu 31:19
4
Saamu 31:14
Ṣùgbọ́n èmí gbẹ́kẹ̀lé ọ, ìwọ OLúWA Mo sọ wí pé, “Ìwọ ní Ọlọ́run mi.”
Ṣàwárí Saamu 31:14
5
Saamu 31:3
Ìwọ pàápàá ni àpáta àti ààbò mi, nítorí orúkọ rẹ, máa ṣe olùtọ́ mi, kí o sì ṣe amọ̀nà mi.
Ṣàwárí Saamu 31:3
6
Saamu 31:5
Ní ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹ̀mí mi lé; ìwọ ni o ti rà mí padà, OLúWA, Ọlọ́run òtítọ́.
Ṣàwárí Saamu 31:5
7
Saamu 31:23
Ẹ fẹ́ OLúWA, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn rẹ̀ mímọ́! OLúWA pa olódodo mọ́, ó sì san án padà fún agbéraga ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.
Ṣàwárí Saamu 31:23
8
Saamu 31:1
Nínú rẹ̀, OLúWA ni mo ti rí ààbò; Má ṣe jẹ́ kí ojú kí ó tì mí; gbà mí nínú òdodo rẹ.
Ṣàwárí Saamu 31:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò