1
Saamu 28:7
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA ni agbára mi àti asà mi; nínú rẹ̀ ni mo gbẹ́kẹ̀lé; àní, ó sì ràn mí lọ́wọ́. Ọkàn mi sì gbé sókè fún ayọ̀ àní pẹ̀lú orin mi mo fi ọpẹ́ fún un.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 28:7
2
Saamu 28:8
OLúWA ni agbára àwọn ènìyàn rẹ̀ òun ni odi ìgbàlà àwọn ẹni ààmì òróró rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 28:8
3
Saamu 28:6
Alábùkún fún ni OLúWA! Nítorí pé ó ti gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.
Ṣàwárí Saamu 28:6
4
Saamu 28:9
Ìwọ gba àwọn ènìyàn rẹ là, kí o sì bùkún àwọn ajogún rẹ; di olùṣọ́-àgùntàn wọn, kí o sì gbé wọn lékè títí ayérayé.
Ṣàwárí Saamu 28:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò