1
Saamu 26:2-3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Wádìí mi wò, Ìwọ OLúWA, kí o sì dán mi wò, dán àyà àti ọkàn mi wò; Nítorí ìfẹ́ ẹ̀ rẹ tí ó dúró ṣinṣin ń bẹ níwájú mi, èmí sì ti rìn nínú òtítọ́ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 26:2-3
2
Saamu 26:1
Ṣe ìdájọ́ mi, OLúWA, nítorí tí mo ti ń rìn nínú ìwà òtítọ́ ọ̀ mi, mo sì ti ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú OLúWA Ǹjẹ́ ẹsẹ̀ mi kì yóò yẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 26:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò