1
Saamu 20:7
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀ wọn lé kẹ̀kẹ́, àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀ wọn lé ẹṣin, ṣùgbọ́n àwa gbẹ́kẹ̀lé orúkọ OLúWA Ọlọ́run wa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 20:7
2
Saamu 20:4
Kí ó fi fún ọ gẹ́gẹ́ bi ti èrò ọkàn rẹ kí ó sì mú gbogbo ìmọ̀ rẹ ṣẹ.
Ṣàwárí Saamu 20:4
3
Saamu 20:1
Kí OLúWA kí ó gbóhùn rẹ ní ọjọ́ ìpọ́njú; kí orúkọ Ọlọ́run Jakọbu kí ó dáàbò bò ọ́.
Ṣàwárí Saamu 20:1
4
Saamu 20:5
Àwa yóò hó fún ayọ̀ nígbà tí o bá di aṣẹ́gun àwa yóò gbé àsíá wa sókè ní orúkọ Ọlọ́run wa. Kí Ọlọ́run kí ó mú gbogbo ìbéèrè rẹ̀ ṣẹ.
Ṣàwárí Saamu 20:5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò