1
Saamu 149:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí OLúWA ní inú dídùn sí àwọn ènìyàn rẹ̀ ó fi ìgbàlà dé àwọn onírẹ̀lẹ̀ ládé
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 149:4
2
Saamu 149:6
Kí ìyìn Ọlọ́run kí ó wà ní ẹnu wọn àti idà olójú méjì ní ọwọ́ wọn.
Ṣàwárí Saamu 149:6
3
Saamu 149:1
Ẹ fi ìyìn fún OLúWA. Ẹ kọrin tuntun sí OLúWA. Ẹ yìn ín ní àwùjọ àwọn ènìyàn mímọ́.
Ṣàwárí Saamu 149:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò