1
Saamu 140:13
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítòótọ́ àwọn olódodo yóò máa fi ọpẹ́ fún orúkọ rẹ; àwọn ẹni dídúró ṣinṣin yóò máa gbé iwájú rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 140:13
2
Saamu 140:1-2
OLúWA, gbà mi lọ́wọ́ ọkùnrin búburú u nì, yọ mí lọ́wọ́ ọkùnrin ìkà a nì; Ẹni tí ń ro ìwà búburú ní inú wọn; nígbà gbogbo ni wọ́n ń rú ìjà sókè sí mi.
Ṣàwárí Saamu 140:1-2
3
Saamu 140:12
Èmi mọ̀ pé, OLúWA yóò mú ọ̀nà olùpọ́njú dúró, yóò sì ṣe ẹ̀tọ́ fún àwọn tálákà
Ṣàwárí Saamu 140:12
4
Saamu 140:4
OLúWA, pa mí mọ́ kúrò lọ́wọ́ àwọn ènìyàn búburú; yọ mí kúrò lọ́wọ́ ọkùnrin ìkà a nì ẹni tí ó ti pinnu rẹ̀ láti bi ìrìn mi ṣubú
Ṣàwárí Saamu 140:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò