1
Saamu 130:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi dúró de OLúWA, ọkàn mi dúró, àti nínú ọ̀rọ̀ rẹ ni èmi ń ṣe ìrètí
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 130:5
2
Saamu 130:4
Nítorí ìdáríjì wà lọ́dọ̀ rẹ, kí a lè máa bẹ̀rù rẹ.
Ṣàwárí Saamu 130:4
3
Saamu 130:6
Ọkàn mi dúró de OLúWA, ju àwọn tí ń ṣọ́nà òwúrọ̀ lọ, àní ju àwọn tí ń ṣọ́nà òwúrọ̀ lọ.
Ṣàwárí Saamu 130:6
4
Saamu 130:2
OLúWA, gbóhùn mi, jẹ́ kí etí rẹ kí o tẹ́ sílẹ̀ sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.
Ṣàwárí Saamu 130:2
5
Saamu 130:1
Láti inú ibú wá ni èmi ń ké pè é ọ́ OLúWA
Ṣàwárí Saamu 130:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò