1
Saamu 125:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLúWA yóò dàbí òkè Sioni, tí a kò lè ṣí ní ìdí, bí kò ṣe pé ó dúró láéláé
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 125:1
2
Saamu 125:2
Bí òkè ńlá ti yí Jerusalẹmu ká, bẹ́ẹ̀ ni OLúWA yí ènìyàn ká láti ìsinsin yìí lọ àti títí láéláé.
Ṣàwárí Saamu 125:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò