1
Saamu 103:2
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Yin OLúWA, ìwọ ọkàn mi, kí o má ṣe gbàgbé gbogbo oore rẹ̀
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Saamu 103:2
2
Saamu 103:3-5
Ẹni tí ó dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ jì ọ́ tí ó sì wo gbogbo ààrùn rẹ̀ sàn, Ẹni tí ó ra ẹ̀mí rẹ padà kúrò nínú kòtò ikú ẹni tí ó fi ìṣeun ìfẹ́ àti ìyọ́nú dé ọ ní adé, Ẹni tí ó fi ohun dídára tẹ́ ọ lọ́rùn kí ìgbà èwe rẹ̀ lè di ọ̀tún bí ti ẹyẹ idì.
Ṣàwárí Saamu 103:3-5
3
Saamu 103:1
Yin OLúWA, ìwọ ọkàn mi; àti gbogbo ohun tí ó wà nínú mi, yín orúkọ rẹ̀ mímọ́.
Ṣàwárí Saamu 103:1
4
Saamu 103:13
Bí baba ti ń ṣe ìyọ́nú sí àwọn ọmọ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni OLúWA ń ṣe ìyọ́nú sí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀
Ṣàwárí Saamu 103:13
5
Saamu 103:12
Bí ìlà-oòrùn ti jìnnà sí ìwọ̀-oòrùn bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe mú ìrékọjá wá jìnnà sí wa.
Ṣàwárí Saamu 103:12
6
Saamu 103:8
OLúWA ni aláàánú àti olóore, ó lọ́ra láti bínú, ó sì pọ̀ ní ìfẹ́.
Ṣàwárí Saamu 103:8
7
Saamu 103:10-11
Òun kì í ṣe sí wa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀ṣẹ̀ wa bẹ́ẹ̀ ni kì í san án fún wa gẹ́gẹ́ bí àìṣedéédéé wa. Nítorí bí ọ̀run ṣe ga sílẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ìfẹ́ rẹ̀ tóbi sí àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀.
Ṣàwárí Saamu 103:10-11
8
Saamu 103:19
OLúWA ti pèsè ìtẹ́ rẹ̀ nínú ọ̀run, ìjọba rẹ̀ ní ó sì borí ohun gbogbo.
Ṣàwárí Saamu 103:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò