1
Òwe 29:25
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ìbẹ̀rù ènìyàn kan yóò sì di ìdẹ̀kùn ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó bẹ̀rù OLúWA wà láìléwu.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Òwe 29:25
2
Òwe 29:18
Níbi tí kò ti sí ìfihàn, àwọn ènìyàn a gbé ìgbé ayé àìbìkítà, ṣùgbọ́n ìbùkún ní fún àwọn tí ń pa òfin mọ́.
Ṣàwárí Òwe 29:18
3
Òwe 29:11
Aláìgbọ́n ènìyàn fi gbogbo ẹnu rẹ̀ bínú ṣùgbọ́n ọlọ́gbọ́n ènìyàn a máa kó ìbínú rẹ̀ ní ìjánu.
Ṣàwárí Òwe 29:11
4
Òwe 29:15
Ọ̀pá ìbániwí ń fún ni ní ọgbọ́n ṣùgbọ́n ọmọ tí a fi sílẹ̀ fúnrarẹ̀ a dójútì ìyá rẹ̀.
Ṣàwárí Òwe 29:15
5
Òwe 29:17
Bá ọmọ rẹ wí, yóò sì fún ọ ní àlàáfíà yóò sì mú inú dídùn wá sí inú ọkàn rẹ.
Ṣàwárí Òwe 29:17
6
Òwe 29:23
Ìgbéraga ènìyàn a máa sọ ọ́ di ẹni ilẹ̀ ṣùgbọ́n onírẹ̀lẹ̀ ènìyàn a máa gba iyì kún iyì.
Ṣàwárí Òwe 29:23
7
Òwe 29:22
Oníbìínú ènìyàn a ru ìjà sókè, onínú-fùfù ènìyàn a sì máa dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀.
Ṣàwárí Òwe 29:22
8
Òwe 29:20
Ǹjẹ́ ó rí ènìyàn tí ń kánjú sọ̀rọ̀? Ìrètí wà fún aláìgbọ́n jù ú lọ.
Ṣàwárí Òwe 29:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò