1
Numeri 23:19
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ọlọ́run kì í ṣe ènìyàn, tí yóò fi purọ́, tàbí ọmọ ènìyàn, tí ó lè yí ọkàn rẹ̀ padà. Ǹjẹ́ ó sọ̀rọ̀ kí ó má ṣe é? Ǹjẹ́ ó ti ṣèlérí kí ó má mu un ṣẹ?
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Numeri 23:19
2
Numeri 23:23
Kò ní àfọ̀ṣẹ sí Jakọbu, tàbí àfọ̀ṣẹ sí àwọn Israẹli. Nísinsin yìí a ó sọ nípa ti Jakọbu àti Israẹli, ‘Wo ohun tí ỌLọ́RUN ti ṣe!’
Ṣàwárí Numeri 23:23
3
Numeri 23:20
Èmi gba àṣẹ láti bùkún; Ó sì ti bùkún, èmi kò sì lè yípadà.
Ṣàwárí Numeri 23:20
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò