1
Mika 7:18
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ta ni Ọlọ́run bí rẹ̀, ẹni tí ó dárí ẹ̀ṣẹ̀ jì, tí ó sì fojú fo ìrékọjá èyí tókù ìní rẹ̀? Kì í dúró nínú ìbínú rẹ̀ láéláé nítorí òun ní inú dídùn sí àánú.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Mika 7:18
2
Mika 7:7
Ṣùgbọ́n ní tèmi, èmi ní ìwòye ní ìrètí sí OLúWA, Èmi dúró de Ọlọ́run olùgbàlà mi; Ọlọ́run mi yóò sì tẹ́tí sí mi.
Ṣàwárí Mika 7:7
3
Mika 7:19
Òun yóò tún padà yọ́nú sí wa; òun yóò tẹ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa mọ́lẹ̀, yóò sì fa gbogbo àìṣedéédéé wa sínú ibú Òkun.
Ṣàwárí Mika 7:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò