1
Ẹkun Jeremiah 3:22-23
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí ìfẹ́ OLúWA tí ó lágbára ni àwa kò fi ṣègbé, nítorí ti àánú rẹ kì í kùnà. Wọ́n jẹ́ ọ̀tún ní àárọ̀; títóbi ni òdodo rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ẹkun Jeremiah 3:22-23
2
Ẹkun Jeremiah 3:24
Mo wí fún ara mi, ìpín mi ni OLúWA; nítorí náà èmi yóò dúró dè ọ́.
Ṣàwárí Ẹkun Jeremiah 3:24
3
Ẹkun Jeremiah 3:25
Dídára ni OLúWA fún àwọn tí ó ní ìrètí nínú rẹ̀, sí àwọn tí ó ń wá a.
Ṣàwárí Ẹkun Jeremiah 3:25
4
Ẹkun Jeremiah 3:40
Ẹ jẹ́ kí a yẹ ọ̀nà wa, kí a sì dán an wò, kí a sì tọ OLúWA lọ.
Ṣàwárí Ẹkun Jeremiah 3:40
5
Ẹkun Jeremiah 3:57
O wá tòsí nígbà tí mo ké pè ọ́, o sì wí pé, “Má ṣe bẹ̀rù.”
Ṣàwárí Ẹkun Jeremiah 3:57
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò