1
Joṣua 21:45
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kò sí ọ̀kan nínú ìlérí rere tí OLúWA ṣe fún ilé Israẹli tí ó kùnà; Gbogbo rẹ̀ ni ó ṣe.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Joṣua 21:45
2
Joṣua 21:44
OLúWA sì fún wọn ní ìsinmi ní gbogbo ọ̀nà, gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣèlérí fún baba ńlá wọn. Kò sì sí ọ̀kankan nínú àwọn ọ̀tá wọn tí ó lè dojúkọ wọ́n. OLúWA sì fi gbogbo àwọn ọ̀tá wọn lé wọn ní ọwọ́.
Ṣàwárí Joṣua 21:44
3
Joṣua 21:43
Báyìí ni OLúWA fún Israẹli ní gbogbo ilẹ̀ tí ó ṣèlérí láti fi fún àwọn baba ńlá wọn. Nígbà tí wọ́n sì gbà á tan wọ́n sì tẹ̀dó síbẹ̀.
Ṣàwárí Joṣua 21:43
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò