1
Jeremiah 5:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Kò ha yẹ kí ẹ bẹ̀rù mi?” ni OLúWA wí. “Kò ha yẹ kí ẹ̀yin ó wárìrì níwájú mi bí? Mo fi yanrìn pààlà Òkun, èyí tí kò le è rékọjá rẹ̀ láéláé. Ìjì lè jà, kò le è borí rẹ̀; wọ́n le è bú, wọn kò le è rékọjá rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jeremiah 5:22
2
Jeremiah 5:1
“Lọ sókè àti sódò àwọn òpópó Jerusalẹmu wò yíká, kí o sì mọ̀, kí o sì wá kiri Bí o bá le è rí ẹnìkan, tí ó jẹ́ olóòtítọ́ àti olódodo, n ó dáríjì ìlú yìí.
Ṣàwárí Jeremiah 5:1
3
Jeremiah 5:31
Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké, àwọn àlùfáà sì ń ṣe àkóso pẹ̀lú àṣẹ ara wọn, àwọn ènìyàn mi sì ní ìfẹ́ sí èyí, kí ni ẹ̀yin yóò ṣe ní òpin?
Ṣàwárí Jeremiah 5:31
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò