1
Jeremiah 24:7
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi yóò fún wọn ní ọkàn láti mọ̀ mí pé, Èmi ni OLúWA. Wọn yóò jẹ́ ènìyàn mi; Èmi ni yóò sì jẹ́ Ọlọ́run wọn; nítorí pé wọn yóò padà sọ́dọ̀ mi pẹ̀lú gbogbo ọkàn wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jeremiah 24:7
2
Jeremiah 24:6
Ojú mi yóò máa ṣọ́ wọn lọ fún rere; Èmi yóò gbé wọn ró, n kò ní já wọn lulẹ̀. Èmi yóò gbìn wọ́n, n kò sì ní fà wọ́n tu.
Ṣàwárí Jeremiah 24:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò