1
Jeremiah 10:23
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi mọ̀ OLúWA wí pé ọ̀nà ènìyàn kì í ṣe ti ara rẹ̀, kì í ṣe fún ènìyàn láti tọ́ ìgbésẹ̀ ara rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jeremiah 10:23
2
Jeremiah 10:6
Kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ OLúWA; o tóbi orúkọ rẹ sì tóbi lágbára.
Ṣàwárí Jeremiah 10:6
3
Jeremiah 10:10
Ṣùgbọ́n OLúWA ni Ọlọ́run tòótọ́, òun ni Ọlọ́run alààyè, ọba ayérayé. Nígbà tí ó bá bínú, ayé yóò wárìrì; orílẹ̀-èdè kò lè fi ara da ìbínú rẹ̀.
Ṣàwárí Jeremiah 10:10
4
Jeremiah 10:24
Tún mi ṣe OLúWA, pẹ̀lú ìdájọ́ nìkan kí o má sì ṣe é nínú ìbínú rẹ, kí ìwọ má ṣe sọ mí di òfo.
Ṣàwárí Jeremiah 10:24
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò