1
Onidajọ 4:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Debora, wòlíì obìnrin, aya Lapidoti ni olórí àti aṣíwájú àwọn ará Israẹli ní àsìkò náà.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Onidajọ 4:4
2
Onidajọ 4:9
Debora dá a lóhùn pé, “ó dára, èmi yóò bá ọ lọ. Ṣùgbọ́n ọlá ìṣẹ́gun tí o ń lọ yìí kò ní jẹ́ tìrẹ, nítorí OLúWA yóò fi Sisera lé obìnrin lọ́wọ́” Báyìí Debora bá Baraki lọ sí Kedeṣi.
Ṣàwárí Onidajọ 4:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò