1
Isaiah 50:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
OLúWA Olódùmarè ti fún mi ni ahọ́n tí a fi iṣẹ́ rán, láti mọ àwọn ọ̀rọ̀ tí ó lè gbé àwọn aláàárẹ̀ ró. O jí mi láràárọ̀, o jí etí mi láti gbọ́ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí à ń kọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isaiah 50:4
2
Isaiah 50:7
Nítorí OLúWA Olódùmarè ràn mí lọ́wọ́; A kì yóò dójútì mí. Nítorí náà ni mo ṣe gbé ojú mi ró bí òkúta akọ èmi sì mọ pé, ojú kò ní tì mí.
Ṣàwárí Isaiah 50:7
3
Isaiah 50:10
Ta ni nínú yín tí ó bẹ̀rù OLúWA tí ó sì ń gbọ́rọ̀ sí ìránṣẹ́ rẹ̀ lẹ́nu? Jẹ́ kí ẹni tí ń rìn ní òkùnkùn tí kò ní ìmọ́lẹ̀, kí ó gbẹ́kẹ̀lé orúkọ OLúWA kí o sì gbẹ́kẹ̀lé Ọlọ́run rẹ̀.
Ṣàwárí Isaiah 50:10
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò