1
Isaiah 5:20
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ègbé ni fún àwọn tí ń pe ibi ní rere, àti rere ní ibi, tí ń fi òkùnkùn ṣe ìmọ́lẹ̀ àti ìmọ́lẹ̀ ṣe òkùnkùn, tí ń fi ìkorò ṣe adùn àti adùn ṣe ìkorò.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isaiah 5:20
2
Isaiah 5:21
Ègbé ni fún àwọn tí ó gbọ́n lójú ara wọn tí wọ́n jáfáfá lójú ara wọn.
Ṣàwárí Isaiah 5:21
3
Isaiah 5:13
Nítorí náà àwọn ènìyàn mi yóò lọ sí ìgbèkùn nítorí òye kò sí fún wọn, ebi ni yóò pa àwọn ọlọ́lá wọn kú; ẹgbàágbèje wọn ni òǹgbẹ yóò sì gbẹ.
Ṣàwárí Isaiah 5:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò