1
Isaiah 3:10
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ sọ fún olódodo pé yóò dára fún wọn, nítorí ní àjẹgbádùn ni wọn yóò jẹ èso iṣẹ́ ẹ wọn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isaiah 3:10
2
Isaiah 3:11
Ègbé ni fún ènìyàn búburú! Ìparun wà lórí i wọn A ó sì san èrè iṣẹ́ tí ọwọ́ wọn ti ṣe fún wọn.
Ṣàwárí Isaiah 3:11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò