1
Isaiah 17:1
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Damasku: “Kíyèsi i, Damasku kò ní jẹ́ ìlú mọ́ ṣùgbọ́n yóò padà di ààtàn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isaiah 17:1
2
Isaiah 17:3
Ìlú olódi ni yóò pòórá kúrò ní Efraimu, àti agbára ọba kúrò ní Damasku; àwọn àṣẹ́kù Aramu yóò dá gẹ́gẹ́ bí ògo ti àwọn Israẹli,” ni OLúWA àwọn ọmọ-ogun wí.
Ṣàwárí Isaiah 17:3
3
Isaiah 17:4
“Ní ọjọ́ náà ni ògo Jakọbu yóò sá; ọ̀rá ara rẹ̀ yóò ṣòfò dànù.
Ṣàwárí Isaiah 17:4
4
Isaiah 17:2
Àwọn ìlú Aroeri ni a ó kọ̀sílẹ̀ fún àwọn agbo ẹran tí yóò máa sùn síbẹ̀, láìsí ẹni tí yóò dẹ́rùbà wọ́n.
Ṣàwárí Isaiah 17:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò