1
Hosea 11:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Mo fi okùn ènìyàn fà wọ́n àti ìdè ìfẹ́. Mo mú àjàgà kúrò ni ọrùn wọn Mo sì fi ara balẹ̀ fún wọn ni oúnjẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Hosea 11:4
2
Hosea 11:1
“Nígbà tí Israẹli wà ní ọmọdé mo fẹ́ràn rẹ̀, mo sì pe ọmọ mi jáde láti Ejibiti wá.
Ṣàwárí Hosea 11:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò