1
Esekiẹli 8:3
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ó na ohun tó dàbí ọwọ́ jáde, ó fi gba mi ní irun orí mú, Ẹ̀mí sì gbé mi sókè sí agbede-méjì ayé àti ọ̀run, ó sì mú mi lọ rí ìran Ọlọ́run, mo sì lọ sí Jerusalẹmu, ṣí ìlẹ̀kùn ẹnu-ọ̀nà òde àríwá níbi tí ère owú tí ó ń mú ni bínú wá níwájú mi
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esekiẹli 8:3
2
Esekiẹli 8:12
Ó sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, ṣé o ti rí ohun tí àwọn àgbàgbà ilé Israẹli ń ṣe nínú òkùnkùn, olúkúlùkù ní yàrá òrìṣà rẹ̀? Wọ́n ní, ‘OLúWA kò rí wa; OLúWA ti kọ̀ ilé náà sílẹ̀.’ ”
Ṣàwárí Esekiẹli 8:12
3
Esekiẹli 8:18
Nítorí náà, èmi yóò fi ìbínú bá wọn wí; èmi kò ní i dá wọn sí bẹ́ẹ̀ ni èmi kò sì ní fojú àánú wò wọ́n. Bí wọ́n tilẹ̀ ń pariwo sí mi létí, èmi kò ní fetí sí wọn.”
Ṣàwárí Esekiẹli 8:18
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò