1
Esekiẹli 43:4-5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ògo OLúWA gba ọ̀nà tí o dojúkọ ìhà ìlà-oòrùn wọ inú ilé Ọlọ́run wá. Mo ni ìrusókè ẹ̀mí, ó sì mú mi lọ inú ilé ìdájọ́, sì kíyèsi ògo OLúWA kún inú ilé Ọlọ́run.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esekiẹli 43:4-5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò