1
Esekiẹli 36:26
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Èmi yóò fún yín ni ọkàn tuntun, èmi yóò sì fi ẹ̀mí tuntun sínú yín; Èmi yóò sì mú ọkàn òkúta kúrò nínú yín, èmi yóò sì fi ọkàn ẹran fún yín.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esekiẹli 36:26
2
Esekiẹli 36:27
Èmi yóò fi ẹ̀mí mi sínú yín, èmi yóò sì mú ki ẹ tẹ̀lé àṣẹ mi, kí ẹ sì fiyèsí àti pa òfin mi mọ́.
Ṣàwárí Esekiẹli 36:27
3
Esekiẹli 36:25
Èmi yóò wọ́n omi tó mọ́ sí yín lára ẹ̀yin yóò sì mọ́; Èmi yóò sì fọ̀ yín mọ́ kúrò nínú gbogbo ìwà èérí yin gbogbo àti kúrò nínú gbogbo òrìṣà yin.
Ṣàwárí Esekiẹli 36:25
4
Esekiẹli 36:28
Ẹ̀yin yóò sì máa gbé ilẹ̀ náà tí mo ti fi fún àwọn baba ńlá yín; ẹ̀yin yóò sì jẹ́ ènìyàn mi èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run yín.
Ṣàwárí Esekiẹli 36:28
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò