1
Esekiẹli 16:49
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“ ‘Wò ó, ẹ̀ṣẹ̀ tí Sodomu ẹ̀gbọ́n rẹ̀ obìnrin ṣẹ̀ nìyìí: Òun àti àwọn ọmọbìnrin rẹ gbéraga, wọ́n jẹ́ alájẹjù àti aláìbìkítà; wọn kò ran tálákà àti aláìní lọ́wọ́
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Esekiẹli 16:49
2
Esekiẹli 16:60
Síbẹ̀ èmi yóò rántí májẹ̀mú tí mo bá ọ ṣe nígbà èwe rẹ, èmi yóò sì bá ọ dá májẹ̀mú láéláé.
Ṣàwárí Esekiẹli 16:60
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò