1
Eksodu 35:30-31
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nígbà náà ni Mose wí fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Wò ó, OLúWA ti yan Besaleli ọmọ Uri, ọmọ Huri, ti ẹ̀yà Juda, Ó sì ti fi ẹ̀mí Ọlọ́run kún un, pẹ̀lú ọgbọ́n, òye, ìmọ̀ àti gbogbo onírúurú iṣẹ́ ọnà
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Eksodu 35:30-31
2
Eksodu 35:35
Ó sì fi ọgbọ́n kún wọn láti ṣe gbogbo onírúurú iṣẹ́, ti oníṣọ̀nà, ti ayàwòrán, ti aránsọ, ti aláṣọ aláró, ti elése àlùkò, ti òdòdó àti ní ọ̀gbọ̀ dáradára àti ti ahunṣọ, gbogbo èyí tí ọ̀gá oníṣẹ́-ọnà àti ayàwòrán ń ṣe.
Ṣàwárí Eksodu 35:35
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò