1
Deuteronomi 34:10
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Láti ìgbà náà kò sì sí wòlíì tí ó dìde ní Israẹli bí i Mose, ẹni tí OLúWA mọ̀ lójúkojú
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Deuteronomi 34:10
2
Deuteronomi 34:9
Joṣua ọmọ Nuni kún fún ẹ̀mí ọgbọ́n nítorí Mose ti gbọ́wọ́ ọ rẹ̀ lé e lórí. Àwọn ọmọ Israẹli sì fetí sí i wọ́n sì ṣe ohun tí Ọlọ́run ti pàṣẹ fún Mose.
Ṣàwárí Deuteronomi 34:9
3
Deuteronomi 34:7
Mose jẹ́ ẹni ọgọ́fà ọdún nígbà tí ó kú, síbẹ̀ ojú rẹ̀ kò ṣe bàìbàì bẹ́ẹ̀ ni agbára rẹ̀ kò dínkù.
Ṣàwárí Deuteronomi 34:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò