1
Deuteronomi 32:4
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Òun ni àpáta, iṣẹ́ ẹ rẹ̀ jẹ́ pípé, gbogbo ọ̀nà an rẹ̀ jẹ́ òdodo. Ọlọ́run olóòtítọ́ tí kò ṣe àṣìṣe kan, Ó dúró ṣinṣin, òdodo àti òtítọ́ ni òun.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Deuteronomi 32:4
2
Deuteronomi 32:39
“Wò ó báyìí pé: èmi fúnra à mi, èmi ni! Kò sí ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn mi. Mo sọ di kíkú mo sì tún sọ di ààyè, Mo ti ṣá lọ́gbẹ́ Èmi yóò sì mu jiná, kò sí ẹni tí ó lè gbà kúrò lọ́wọ́ ọ̀ mi.
Ṣàwárí Deuteronomi 32:39
3
Deuteronomi 32:3
Èmi yóò kókìkí orúkọ OLúWA, Háà, ẹ yin títóbi Ọlọ́run wa!
Ṣàwárí Deuteronomi 32:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò