1
Deuteronomi 26:19
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Òun sì jẹ́wọ́ pé, òun yóò gbé ọ sókè ju gbogbo orílẹ̀-èdè tí òun ti dá lọ, ní ìyìn, ní òkìkí àti ní ọlá; kí ìwọ kí ó le jẹ́ ènìyàn mímọ́ sí OLúWA Ọlọ́run rẹ gẹ́gẹ́ bí òun ti ṣe ìlérí.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Deuteronomi 26:19
2
Deuteronomi 26:18
Ní òní ni OLúWA jẹ́wọ́ rẹ pé ìwọ ni ènìyàn òun, ilé ìṣúra rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òun ti ṣe ìlérí, àti pé ìwọ yóò máa pa gbogbo àṣẹ rẹ̀ mọ́.
Ṣàwárí Deuteronomi 26:18
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò