1
Deuteronomi 24:16
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Baba kò gbọdọ̀ kú fún àwọn ọmọ wọn tàbí kí àwọn ọmọ kú fún baba wọ́n; olúkúlùkù ní láti kú fún ẹ̀ṣẹ̀ òun tìkára rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Deuteronomi 24:16
2
Deuteronomi 24:5
Bí ọkùnrin kan bá ṣẹ̀ṣẹ̀ gbéyàwó, o kò gbọdọ̀ ran lọ sí ogun tàbí kí ó ní iṣẹ́ kan láti ṣe. Ó ní láti ní òmìnira fún ọdún kan kí ó dúró sílé kí ó sì mú inú dídùn bá ìyàwó rẹ̀ tí ó fẹ́.
Ṣàwárí Deuteronomi 24:5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò