1
Deuteronomi 15:10
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Fún un tọkàntọkàn, láìsí ìkùnsínú, nítorí èyí, OLúWA Ọlọ́run rẹ yóò bùkún fún ọ nínú iṣẹ́ ọwọ́ rẹ, àti gbogbo ìdáwọ́lé rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Deuteronomi 15:10
2
Deuteronomi 15:11
A kò lè fẹ́ tálákà kù ní ilẹ̀ náà ní ìgbà gbogbo, mo pàṣẹ fún un yín láti lawọ́ sí àwọn arákùnrin yín, sí àwọn tálákà àti sí àwọn aláìní, ní ilẹ̀ ẹ yín.
Ṣàwárí Deuteronomi 15:11
3
Deuteronomi 15:6
Nítorí pé OLúWA Ọlọ́run yín yóò bùkún un yín bí ó ti ṣèlérí, ẹ̀yin yóò sì máa yá ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè ẹ kì yóò sì tọrọ. Ẹ ó ṣàkóso ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè, ṣùgbọ́n kò sí orílẹ̀-èdè tí yóò lè jẹ ọba lé e yín lórí.
Ṣàwárí Deuteronomi 15:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò