1
Amosi 8:11
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Ọjọ́ ń bọ̀,” ni OLúWA Olódùmarè wí, “nígbà tí èmi yóò rán ìyàn sí ilẹ̀ náà, kì í ṣe ìyàn oúnjẹ tàbí òǹgbẹ fún omi. Ṣùgbọ́n ìyàn gbígbọ́ ọ̀rọ̀ OLúWA.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Amosi 8:11
2
Amosi 8:12
Àwọn ènìyàn yóò rìn kiri láti Òkun dé Òkun wọn yóò sì máa rìn ká láti gúúsù sí àríwá, wọn yóò máa wá ọ̀rọ̀ OLúWA ṣùgbọ́n wọn kì yóò rí i.
Ṣàwárí Amosi 8:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò