1
Ìṣe àwọn Aposteli 12:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Nítorí náà wọn fi Peteru pamọ́ sínú túbú; ṣùgbọ́n ìjọ ń fi ìtara gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run fún un.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 12:5
2
Ìṣe àwọn Aposteli 12:7
Sì wò ó, angẹli Olúwa farahàn, ìmọ́lẹ̀ sì mọ́ nínú túbú; ó sì lu Peteru pẹ́pẹ́ lẹ́gbẹ̀ẹ́, ó jí i, ó ni, “Dìde kánkán!” Ẹ̀wọ̀n sí bọ́ sílẹ̀ kúrò ní ọwọ́ Peteru.
Ṣàwárí Ìṣe àwọn Aposteli 12:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò