1
2 Samuẹli 7:22
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
“Ìwọ sì tóbi, OLúWA Olódùmarè! Kò sì sí ẹni tí ó dàbí rẹ, kò sì sí Ọlọ́run kan lẹ́yìn rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí gbogbo èyí tí àwa fi etí wá gbọ́.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 2 Samuẹli 7:22
2
2 Samuẹli 7:13
Òun ó sì kọ́ ilé fún orúkọ mi, èmi yóò sì fi ìdí ìjọba rẹ kalẹ̀ láéláé.
Ṣàwárí 2 Samuẹli 7:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò