1
2 Kọrinti 13:5
Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní
Ẹ máa wádìí ara yín, bí ẹ̀yin bá wà nínú ìgbàgbọ́; ẹ máa dán ara yín wò. Tàbí ẹ̀yin fúnrayín kò mọ ara yín pé Jesu Kristi wá nínú yín? Àfi bí ẹ̀yin bá jẹ́ àwọn tí a tanù.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí 2 Kọrinti 13:5
2
2 Kọrinti 13:14
Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa, àti ìfẹ́ Ọlọ́run, àti ìdàpọ̀ ti Èmí Mímọ́, kí ó wà pẹ̀lú gbogbo yín.
Ṣàwárí 2 Kọrinti 13:14
3
2 Kọrinti 13:11
Ní àkótán, ará ó dì gbòóṣe, ẹ ṣe àtúnṣe ọ̀nà yín, ẹ tújúká, ẹ jẹ́ onínú kan, ẹ máa wà ní àlàáfíà, Ọlọ́run ìfẹ́ àti ti àlàáfíà yóò wà pẹ̀lú yín.
Ṣàwárí 2 Kọrinti 13:11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò